Hymn 597: Praise, Honour, Grace and blessing

Iyin, ola, ogo, ’bukun


    Iyìn, ọla, ogo, ‘bukun,
    L’awa nfi f’orukọ Rẹ:
    T’agba t’ewe jumọ kọrin,
    Lati yìn Olugbala;
    B’awọn mimọ l’ọrun ti nyìn,
    A wolẹ niwaju Rẹ;
    B’ Angẹl ti nsìn niwaju Rẹ,
    Bẹ k’a ṣe ‘fẹ Rẹ laiye.