Hymn 599: Glory and honour and all power

Ogo, ola, at’ agbara

    Ogo, ọla, at’ agbara,
    Ni f’ Ọd’agutan titi;
    Jesu l’Olurapada wa,
    Halleluya ! titi lai.